Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 4:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí wọ́n ṣe pàṣẹ pé kí wọn fi kùkùté àti gbòǹgbò igi náà sílẹ̀, èyí túmọ̀ sí wí pé a ó dá ìjọba rẹ padà fún ọ lẹ́yìn ìgbà tí o bá ti mọ̀ wí pé, Ọ̀run jọba.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 4

Wo Dáníẹ́lì 4:26 ni o tọ