Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 4:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A ó lé ọ jáde kúrò láàrin ènìyàn, ìwọ yóò sì máa gbé láàrin ẹranko búburú: ìwọ yóò jẹ koríko bí i màlúù, ìrì ọ̀run yóò sì sẹ̀ sára rẹ. Ìgbà méje yóò sì kọjá lórí ì rẹ, títí ìwọ yóò fi mọ̀ wí pé Ọ̀gá Ògo ń jọba lórí ìjọba ènìyàn, ó sì ń fi fún ẹni tí ó bá wù ú.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 4

Wo Dáníẹ́lì 4:25 ni o tọ