Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 4:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí tí ewé e rẹ̀ lẹ́wà, tí èṣo rẹ̀ si pọ̀, nínú èyí tí oúnjẹ sì wà fún gbogbo ẹ̀dá, lábẹ́ èyí tí àwọn ẹranko ìgbó ń gbé, lórí ẹ̀ka èyí ti àwọn ẹyẹ ojú ọ̀run ní ibùgbé wọn.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 4

Wo Dáníẹ́lì 4:21 ni o tọ