Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 4:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Igi tí ìwọ rí, tí ó dàgbà, tí ó sì lágbára, tí orí i rẹ̀ sì ń kan ọ̀run, tí ó lẹ́wà àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ èso, tí ó ń pèsè oúnjẹ fún gbogbo ènìyàn, tí ó ṣe ààbò lórí ẹranko igbó àti èyí tí ẹ̀ka rẹ̀ pèsè àyè fún ẹyẹ ojú ọ̀run.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 4

Wo Dáníẹ́lì 4:20 ni o tọ