Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 4:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ ọba ni igi náà, ìwọ ti dàgbà, o sì lágbára, títóbi i rẹ ga ó sì kan ọ̀run, ìjọba rẹ sì gbilẹ̀ títí dé òpin ayé.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 4

Wo Dáníẹ́lì 4:22 ni o tọ