Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 3:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nebukadinéṣárì wí fún wọn wí pé, “Ṣé òtítọ́ ni, Sádírákì, Méṣákì àti Àbẹ́dinígò wí pé ẹ̀yin kò sin òrìṣà mi àti pé ẹ̀yin kò fi orí balẹ̀ fún ère wúrà tí èmi gbé kalẹ̀.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 3

Wo Dáníẹ́lì 3:14 ni o tọ