Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 3:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ìsinsìnyìí, tí ẹ̀yin bá ti gbọ́ ohùn ìwo, fèrè, dùùrù, ohun èlò orin olókun, ìpè àti onírúurú orin, bí ẹ̀yin bá ṣetan láti wólẹ̀ kí ẹ̀yin fi orí balẹ̀ fún ère tí mo gbé kalẹ̀ ó dára. Ṣùgbọ́n tí ẹ̀yìn bá kọ̀ láti sìn ín, lójúkan náà ni a ó gbé e yín jù sínú iná ìléru. Ǹjẹ́, ta ni Ọlọ́run náà tí yóò gbà yín kúrò lọ́wọ́ mi?”

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 3

Wo Dáníẹ́lì 3:15 ni o tọ