Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 3:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni Nebukadinéṣárì pàṣẹ ní ìrunú àti ìbínú pé kí a mú Ṣádírákì, Méṣákì àti Àbẹ́dinígò wá, wọ́n sì mú wọn wá síwájú ọba.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 3

Wo Dáníẹ́lì 3:13 ni o tọ