Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 11:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ọba ìhà Gúṣù yóò di alágbára ṣùgbọ́n ọ̀kan lára àwọn aláṣẹ rẹ̀ yóò di alágbára jùú lọ, yóò sì ṣe àkóso ìjọba rẹ̀ pẹ̀lú agbára ńlá.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 11

Wo Dáníẹ́lì 11:5 ni o tọ