Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 11:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́yìn ìgbà tí ó bá fi ara hàn tán, ìjọba rẹ̀ yóò fọ́, yóò sì pín sí mẹ́rin ní origun mẹ́rẹ̀ẹ̀rin ayé, ìjọba náà kò sì sọ́wọ́ àwọn ìran rẹ̀ tàbí kí ó ní agbára tí ó ń lò tẹ́lẹ̀, nítorí, a ó fa ìjọba rẹ̀ tu a ó sì fi fún àwọn mìíràn.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 11

Wo Dáníẹ́lì 11:4 ni o tọ