Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 10:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì wí pé, “Má se bẹ̀rù, ìwọ ọkùnrin tí a yàn fẹ́ gidigidi.” Bí ó ti sọ̀rọ̀ fún mi, ara à mí sì le, mo sọ pé, “Má a wí Olúwa mi, níwọ̀n ìgbà tí o ti fún mi ní agbára.”

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 10

Wo Dáníẹ́lì 10:19 ni o tọ