Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 10:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà, ni ó wí pé, “Sé o mọ ìdí tí mo fi tọ̀ ọ́ wá? Láìpẹ́ èmi yóò yípadà lọ bá àwọn ọmọ aládé Páṣíà jà, nígbà tí mo bá lọ àwọn ọmọ aládé Gíríkì yóò wá;

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 10

Wo Dáníẹ́lì 10:20 ni o tọ