Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 1:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n Dáníẹ́lì pinnu ní ọkàn ara rẹ̀ pé òun kò ní ba ara òun jẹ́ pẹ̀lú oúnjẹ àti wáìnì ọba, nígbà náà ni ó gba ààyè lọ́wọ́ olórí àwọn ìwẹ̀fà wí pé òun kò fẹ́ ba ara òun jẹ́ ní ọ̀nà yìí.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 1

Wo Dáníẹ́lì 1:8 ni o tọ