Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 1:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olórí àwọn ìwẹ̀fà fún wọn ní orúkọ tuntun: Ó fún Dáníẹ́lì ní Beliteṣáṣárì, ó fún Hananíáyà ní Sádírákì, ó fún Mísáẹ́lì ní Mésákì àti Áṣáríyà ní Àbẹ́dinígò.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 1

Wo Dáníẹ́lì 1:7 ni o tọ