Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 1:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba pèsè oúnjẹ ojoojúmọ́ àti wáìnì láti orí tábìlì i rẹ̀ fún wọn, ó sì kọ́ wọn fún ọdún mẹ́ta. Lẹ́yìn náà ni wọn yóò bẹ̀rẹ̀ sí í ṣiṣẹ́ fún ọba.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 1

Wo Dáníẹ́lì 1:5 ni o tọ