Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ámósì 7:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa sì bi mi pé, “Ámósì, kí ni ìwọ rí?”Mo dáhùn pé, “Okùn-ìwọ̀n.”Nígbà náà ni Olúwa wí pé, “Wòó, Èmí ń gbé okùn-ìwọ̀n kalẹ láàárin àwọn Ísírẹ́lì ènìyàn mi; Èmi kì yóò sì tún kọjá lọ́dọ̀ wọn mọ́

Ka pipe ipin Ámósì 7

Wo Ámósì 7:8 ni o tọ