Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ámósì 7:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí ni ohun tí Olúwa Ọlọ́run fi hàn mí: Ó pèsè ọwọ́ esú lẹ́yìn ìgbà tí a kórè ìpín ọba, ní ìgbà ti èso ẹ̀ẹ̀kejì ń jáde bọ̀.

Ka pipe ipin Ámósì 7

Wo Ámósì 7:1 ni o tọ