Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ámósì 6:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ègbé ni fún ẹ̀yin tí ará rọ̀ ní Síónìàti ẹ̀yin tí ẹ wà ní abẹ́ ààbò ní òkè Samaríààti ẹ̀yin olókìkí orílẹ̀-èdètí ẹ̀yin ènìyàn Ísírẹ́lì máa ń tọ̀ ọ́ wá

Ka pipe ipin Ámósì 6

Wo Ámósì 6:1 ni o tọ