Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ámósì 5:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Gbọ́ ọ̀rọ̀ yìí, ìwọ ilé Ísírẹ́lì, ìpohùnréré ẹkún tí mo ṣe nípa rẹ:

2. “Wúndíá Ísírẹ́lì ṣubúláì kò sì le padà dìdeó di ẹni ìkọ̀tì ní ilẹ̀ rẹ̀kò sí ẹni tí yóò gbé e nàró.”

3. Èyí ni ohun tí Olúwa ọ̀gá ògo wí:“Ìlú tí ẹgbẹ̀rún alágbára ti jáde,yóò dín ku ọgọ́run ní Ísírẹ́lì.Ìlú tí ọgọ́run alàgbà ti jádeyóò ṣẹ́ku ẹni mẹ́wàá.”

Ka pipe ipin Ámósì 5