Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ámósì 5:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí ni ohun tí Olúwa ọ̀gá ògo wí:“Ìlú tí ẹgbẹ̀rún alágbára ti jáde,yóò dín ku ọgọ́run ní Ísírẹ́lì.Ìlú tí ọgọ́run alàgbà ti jádeyóò ṣẹ́ku ẹni mẹ́wàá.”

Ka pipe ipin Ámósì 5

Wo Ámósì 5:3 ni o tọ