Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ámósì 3:13-15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

13. “Gbọ́ èyí kí o sì jẹ́rìí nípa ilé Jákọ́bù,” ni Olúwa wí, Olúwa Ọlọ́run alágbára.

14. “Ní ọjọ́ tí mo fìyà jẹ Ísírẹ́lì lórí ẹ̀ṣẹ̀ wọn,Èmi yóò pa pẹpẹ Bétélì run;ìwo pẹpẹ ni a ó ké kúròyóò sì wó lulẹ̀.”

15. “Èmi yóò wó ilé òtútùlulẹ̀ pẹ̀lú ilé ẹ̀ẹ̀rùn;ilé tí a fi eyín erin ṣe lọ́ṣọ̀ọ́ yóò ṣègbéa ó sì pa ilé ńlá náà run,”ni Olúwa wí.

Ka pipe ipin Ámósì 3