Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ámósì 3:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Èmi yóò wó ilé òtútùlulẹ̀ pẹ̀lú ilé ẹ̀ẹ̀rùn;ilé tí a fi eyín erin ṣe lọ́ṣọ̀ọ́ yóò ṣègbéa ó sì pa ilé ńlá náà run,”ni Olúwa wí.

Ka pipe ipin Ámósì 3

Wo Ámósì 3:15 ni o tọ