Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 61:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A ó mọ ìrandíran wọn láàrin àwọn orílẹ̀ èdèàti àwọn ìran wọn láàrin àwọn ènìyànGbogbo àwọn tí ó bá rí wọn yóò mọ̀ péwọ́n jẹ́ àwọn ènìyàn tí Olúwa ti bùkún.”

Ka pipe ipin Àìsáyà 61

Wo Àìsáyà 61:9 ni o tọ