Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 61:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nítorí Èmi, Olúwa fẹ́ràn ìdájọ́ òdodo;mo kórìíra olè jíjà àti ẹ̀ṣẹ̀Ní òtítọ́ mi èmi yóò ṣẹ̀san fún wọnèmi yóò sì dá májẹ̀mú ayérayé pẹ̀lúu wọn.

Ka pipe ipin Àìsáyà 61

Wo Àìsáyà 61:8 ni o tọ