Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 60:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọ̀wọ́ ràkunmí yóò bo gbogbo ilẹ̀ rẹ,àwọn ọ̀dọ́ ràkunmí Mídíánì àti Ẹfà.Àti gbogbo wọn létí Ṣèbà yóò wá,wọn yóò mú Góòlù àti tùràrí lọ́wọ́tí wọn yóò sì máa kéde ìyìn Olúwa.

Ka pipe ipin Àìsáyà 60

Wo Àìsáyà 60:6 ni o tọ