Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 60:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni ìwọ yóò wò tí ojú rẹ yóò máa dán,ọkàn rẹ yó fó yó sì kún fún ayọ̀;ọrọ̀ inú òkun ni a ó kò wá sọ́dọ̀ rẹ,sí ọ̀dọ̀ rẹ ni ọrọ̀ àwọn orílẹ̀ èdè yóò wá.

Ka pipe ipin Àìsáyà 60

Wo Àìsáyà 60:5 ni o tọ