Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 60:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo agbo ẹran Kédárì ni a ó kójọ sọ́dọ̀ rẹ,àwọn àgbò ti Nébáíótì yóò sìn ọ́;wọn yóò jẹ́ ọrẹ ìtẹ́wọ́gbà lóríi pẹpẹ mi,bẹ́ẹ̀ ni n ó sì ṣe tẹ́ḿpìlì ògo mi lọ́ṣọ̀ọ́.

Ka pipe ipin Àìsáyà 60

Wo Àìsáyà 60:7 ni o tọ