Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 60:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Gbé ojú rẹ ṣókè kí o sì wò yíká rẹ:Gbogbo wọn gbárajọ wọ́n sì wá sọ́dọ̀ rẹ;àwọn ọmọ rẹ wá láti ọ̀nà jíjìn,àti àwọn ọ̀dọ́mọbìnrìn rẹ ni a gbé ní apá.

Ka pipe ipin Àìsáyà 60

Wo Àìsáyà 60:4 ni o tọ