Àìsáyà 6:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)
Nígbà náà ni mo wí pé, “Báwo ni yóò ti pẹ́ tó Olúwa?”Òun sì dáhùn pé:“Títí tí gbogbo ìlú ńlá yóò fi dahoroláìsí olùgbé nínú un rẹ̀ mọ́,títí tí gbogbo ilé yóò fi di ìkọ̀sílẹ̀tí gbogbo ilé yóò sì di àlàpà àti ahoro,