Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 6:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mú kí àyà àwọn ènìyàn wọ̀nyí yigbì,mú kí wọn kútíkí o sì pa ojú wọn dé.Bí kò ṣe bẹ́ẹ̀, wọn yóò fi ojú u wọn ríran,ki wọn má ba à fi etíi wọn gbọ́ràn,kí òye máa ba à yé wọn ní ọkàn an wọnkí wọn má ba à yípadà kí a má ba à sì wò wọ́n sàn.”

Ka pipe ipin Àìsáyà 6

Wo Àìsáyà 6:10 ni o tọ