Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 59:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí èyí ni ẹ̀tọ́ fi jìnnà sí wa,àti tí òdodo kò fi tẹ̀wá lọ́wọ́.A ń wá ìmọ́lẹ̀, ṣùgbọ́n gbogbo rẹ jẹ́ òkùnkùn;fún ìmọ́lẹ̀, ṣùgbọ́n à ń rìn nínú òjìji.

Ka pipe ipin Àìsáyà 59

Wo Àìsáyà 59:9 ni o tọ