Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 59:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọ̀nà àlàáfíà èyí ni wọn kò mọ̀;kò sí òdodo ní ojú ọ̀nà wọnwọ́n ti sọ wọ́n dì ọ̀nà kọ́rọkọ́rọ,kò sí ẹni tí ó tọ ọ̀nà yìí tí yóò rí àlàáfíà.

Ka pipe ipin Àìsáyà 59

Wo Àìsáyà 59:8 ni o tọ