Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 58:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

‘Èéṣe tí àwa fi ń gbààwẹ̀,’ ni wọ́n wí,‘tí ìwọ kò sì tí ì rí?Èéṣe tí àwa fi rẹra wa sílẹ̀,tí ìwọ kò sì tí ì ṣe àkíyèsí?’“Ṣíbẹ̀ ṣíbẹ̀ ní ọjọ́ ààwẹ̀ yín, ẹ̀yin ń ṣe bí ó ti wù yínẹ sì ń pọ́n àwọn òṣìṣẹ́ yín gbogbo lójú.

Ka pipe ipin Àìsáyà 58

Wo Àìsáyà 58:3 ni o tọ