Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 58:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ààwẹ̀ yín sì parí nínú ìjà àti asọ̀,àti lílu ọmọnìkejì ẹni pẹ̀lú ẹṣẹ́ ìkà.Ẹ̀yin kò le è gbààwẹ̀ bí ẹ ti ń ṣe lónìíkí ẹ sì retí kí a gbọ́ ohùn un yín ní ibi gíga.

Ka pipe ipin Àìsáyà 58

Wo Àìsáyà 58:4 ni o tọ