Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 58:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Bí ìwọ bá pa ẹṣẹ̀ rẹ mọ́ kúrò nínú bíba ọjọ́-ìsinmi jẹ́,àti síse bí ó ti wù ọ́ ni ọjọ́ mímọ́ mi,bí ìwọ bá pe ọjọ-ìsinmi ní ohun dídùnàti ọjọ́ mímọ́ Olúwa ní ohun ọ̀wọ̀àti bí ìwọ bá bu ọlá fún un láti máa bá ọ̀nà tìrẹ lọàti láti má ṣe bí ó ti wù ọ́ tàbíkí o máa ṣọ̀rọ̀ òòrayè,

Ka pipe ipin Àìsáyà 58

Wo Àìsáyà 58:13 ni o tọ