Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 58:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

nígbà náà ni ìwọ yóò ní ayọ̀ nínú Olúwa rẹ,èmi yóò sì jẹ́ kí ìwọ kí ó máa gun ibi gíga ilẹ̀ ayé,àti láti máa jàdídùn ìní tiJákọ́bù baba rẹ.”Ẹnu Olúwa ni ó ti sọ̀rọ̀.

Ka pipe ipin Àìsáyà 58

Wo Àìsáyà 58:14 ni o tọ