Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 57:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ère tí ó wà ní àárin òkúta dídánwọ̀n n nì, nínú kòtò jínjìn ni ìpín in yín;àwọn, àwọ̀n ni ìpín in yín.Bẹ́ẹ̀ ni, sí wọn ni ẹ ti ta ọrẹ ohun mímu yín sílẹ̀àti láti ta ọrẹ oníhóró.Nítorí àwọn nǹkan wọ̀nyí, ǹjẹ́ ó yẹkí n dáwọ́ dúró?

Ka pipe ipin Àìsáyà 57

Wo Àìsáyà 57:6 ni o tọ