Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 57:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ gbinájẹ fún ìṣekúṣe láàrin igi óákùàti lábẹ́ gbogbo igi tí ń gbilẹ̀;ẹ fi àwọn ọmọ yín rúbọ nínú kòtò jínjìnàti lábẹ́ àwọn pàlàpálá òkúta.

Ka pipe ipin Àìsáyà 57

Wo Àìsáyà 57:5 ni o tọ