Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 56:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Wá,” ni igbe ẹnìkọ̀ọ̀kan wọn, “fún mi ní ọtí wáìnì!Jẹ́ kí a mu ọtí bíà wa lámu yóọ̀la yóò sì dàbí òní,tàbí kí ó dára jù bẹ́ẹ̀ lọ.”

Ka pipe ipin Àìsáyà 56

Wo Àìsáyà 56:12 ni o tọ