Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 56:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n jẹ́ àwọn ajá tí ó kúndùn púpọ̀;wọn kì í ní ànító.Wọ́n jẹ́ olùṣọ́ àgùntàn tí kò ní òye;olúkúlùkù ń yà sọ́nà ara rẹ̀,ẹnìkọ̀ọ̀kan wọn sì wá ère tirẹ̀.

Ka pipe ipin Àìsáyà 56

Wo Àìsáyà 56:11 ni o tọ