Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 56:10-12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

10. Àwọn olùṣọ́ Ísírẹ́lì fọ́jú,gbogbo wọn ṣe aláìní ìmọ̀;Gbogbo wọn jẹ́ adití ajá,wọn kò lè gbó;wọ́n sùn sílẹ̀ wọ́n ń lálàá,wọ́n fẹ́ràn láti máa sùn.

11. Wọ́n jẹ́ àwọn ajá tí ó kúndùn púpọ̀;wọn kì í ní ànító.Wọ́n jẹ́ olùṣọ́ àgùntàn tí kò ní òye;olúkúlùkù ń yà sọ́nà ara rẹ̀,ẹnìkọ̀ọ̀kan wọn sì wá ère tirẹ̀.

12. “Wá,” ni igbe ẹnìkọ̀ọ̀kan wọn, “fún mi ní ọtí wáìnì!Jẹ́ kí a mu ọtí bíà wa lámu yóọ̀la yóò sì dàbí òní,tàbí kí ó dára jù bẹ́ẹ̀ lọ.”

Ka pipe ipin Àìsáyà 56