Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 55:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ẹ wá, gbogbo ẹ̀yin tí òrùngbẹ ń gbẹ,ẹ wá sí ibi omi;àti ẹ̀yin tí kò ní owó;ẹ wá, ẹ rà kí ẹ sì jẹ!Ẹ wá ra wáìnì àti mílíìkìláìsí owó àti láìdíyelé.

Ka pipe ipin Àìsáyà 55

Wo Àìsáyà 55:1 ni o tọ