Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 55:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èéṣe tí ẹ fi ń ná owó fún èyí tí kì í ṣe àkàrààti làálàá yín lórí ohun tí kì í tẹ́nilọ́rùn?Tẹ́tísílẹ̀, tẹ́tí sí mi, kí ẹ sì jẹ èyí tí ó dára,bẹ́ẹ̀ ni ọkàn yín yóò láyọ̀ nínú ọrọ̀ tí ó bójúmu.

Ka pipe ipin Àìsáyà 55

Wo Àìsáyà 55:2 ni o tọ