Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 50:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí mo wá, èéṣe tí a kò fi rí ẹnìkan?Nígbà tí mo pè, èéṣe tí kò fi sí ẹnìkan láti dáhùn?Ọwọ́ mi a kúrú láti gbà ọ́?Èmi kò ha ní agbára láti gbà ọ́ bí?Nípa ìbáwí lásán, Èmi gbẹ omi òkun,Èmi yí àwọn odò sí aṣálẹ̀;àwọn ẹja wọn rà fún àìsí omiwọ́n sì kú fún òùngbẹ.

Ka pipe ipin Àìsáyà 50

Wo Àìsáyà 50:2 ni o tọ