Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 50:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ohun tí Olúwa wí níyìí:“Níbo ni ìwé-ẹ̀rí ìkọ̀sílẹ̀ìyá rẹ wàèyí tí mo fi lé e lọ?Tàbí èwo nínú àwọn olùyánilówó mini mo tà ọ́ fún?Nítorí ẹ̀ṣẹ̀ rẹ ni a fi tà ọ́;nítorí àìṣedéédéé rẹ ni a fi lé ìyá rẹ lọ.

Ka pipe ipin Àìsáyà 50

Wo Àìsáyà 50:1 ni o tọ