Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 49:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láti sọ fún àwọn ìgbèkùn pé, ‘Ẹ jáde wá’àti fún àwọn tí ó wà nínú òkùnkùn pé, ‘Ẹ gba òmìnira!’“Wọn yóò máa jẹ ní ẹ̀bá ọ̀nààti koríko tútù lórí òkè aláìléwéko.

Ka pipe ipin Àìsáyà 49

Wo Àìsáyà 49:9 ni o tọ