Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 49:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ebi kì yóò pa wọ́n bẹ́ẹ̀ ni òrùngbẹ kì yóò gbẹ wọ́n,tàbí kí ooru inú aṣálẹ̀ tàbí òòrùn kí ó pa wọ́n.Ẹni tí ó ṣàánú fún wọn ni yóò máa tọ́ wọn,tí yóò sì mú wọn lọ sí ibi oríṣun omi.

Ka pipe ipin Àìsáyà 49

Wo Àìsáyà 49:10 ni o tọ