Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 49:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ohun tí Olúwa wí nìyìí:“Ní àkókò ojú rere mi, èmi yóò dá ọ lóhùn,àti ní ọjọ́ ìgbàlà, èmi yóò ràn ọ́ lọ́wọ́;Èmi yóò pa ọ́ mọ́, n ó sì ṣe ọ́láti jẹ́ májẹ̀mú fún àwọn ènìyàn,láti mú ilẹ̀ padà bọ̀ sípòàti láti ṣe àtúnpín ogún rẹ̀ tí ó ti dahoro,

Ka pipe ipin Àìsáyà 49

Wo Àìsáyà 49:8 ni o tọ