Àìsáyà 49:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)
Èmi yóò mú kí àwọn aninilára rẹ̀ jẹẹran ara wọn;wọn yóò mu ẹ̀jẹ̀ ara wọn yóbí ẹnii mu wáìnì.Nígbà náà ni gbogbo ọmọnìyàn yóò mọ̀pé Èmi, Olúwa, èmi ni Olùgbàlà rẹ,Olùdáǹdè rẹ, Alágbára kanṣoṣo ti Jákọ́bù.”