Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 49:25-26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

25. Ṣùgbọ́n ohun tí Olúwa wí níyìí:“Bẹ́ẹ̀ ni, a ó gba àwọn ìgbékùn lọ́wọ́ àwọn jagunjagun,àti ìkógun lọ́wọ́ àwọn akíkanjú;Ẹni tí ó bá ọ jà ni èmi ó bá jà,àti àwọn ọmọ rẹ ni èmi ó gbàlà.

26. Èmi yóò mú kí àwọn aninilára rẹ̀ jẹẹran ara wọn;wọn yóò mu ẹ̀jẹ̀ ara wọn yóbí ẹnii mu wáìnì.Nígbà náà ni gbogbo ọmọnìyàn yóò mọ̀pé Èmi, Olúwa, èmi ni Olùgbàlà rẹ,Olùdáǹdè rẹ, Alágbára kanṣoṣo ti Jákọ́bù.”

Ka pipe ipin Àìsáyà 49